Historically and contemporarily, Ifaki-Ekiti as a community and the indigenes are unique people. The uniqueness of Ifaki is exemplified in the composition of the four quarters with different ancestral links with some neighbouring Ekiti towns and communities, the traditional native administrative system, cultures, traditions, outstanding accomplishments of some of the exemplary indigenes who stood out in their respective callings and recorded firsts in Ekiti-State as well as the traditional festivals that give Ifaki her identity as a distinct community in the Yoruba nation.
Nestled in the heart of Ekiti State, Ifaki is rapidly emerging as a jewel of opportunity, capturing the attention of investors and developers alike.
This nodal town, strategically located near Ado Ekiti, the state capital, offers a compelling landscape for real estate and commercial ventures. Its potential mirrors that of Ikorodu in contemporary Lagos State, highlighting Ifaki's unique position in the region's growth narrative.
Ifaki Ekiti Ilu Olokiki
llu tatedo sorioke giga
llu towa larin gbogbo Ekiti.
llosiwaju re la o ma wa llu toje ilu rere
Alafia yoo je ti re
2. Ejeka gbe llu Ifaki yi ga
Kaparapo ko le dara
Kajapere fun llu miran
Isokan ma lo ye gbogbo wa
E gba wopo sohun rere
3. Egbe llu Ifaki yi laruge
Ire wole o to wa wa
Si llu to dara to si lewa
llu tie emi ko le gbagbe lai
Gbogbo Ifaki kesima yo
Orire wa yoo bawa kale
4. Ohun ta se loni itan ni
Ajeji Owo ko gberu dori
Wa ko ni sowa lori
Efife han si ara yin
A o ko ere oko dele
5. Omo Ifaki to wa lajo
E ma kore rere wale
Ranti pe ile labo oko
E o kore oko dele
lle koko leye oko nke
E mase gbagbe Ili Ifaki
Ifaki Ekiti Ilu Olokiki
llu tatedo sorioke giga
llu towa larin gbogbo Ekiti.
llosiwaju re la o ma wa llu toje ilu rere
Alafia yoo je ti re
2. Ejeka gbe llu Ifaki yi ga
Kaparapo ko le dara
Kajapere fun llu miran
Isokan ma lo ye gbogbo wa
E gba wopo sohun rere
3. Egbe llu Ifaki yi laruge
Ire wole o to wa wa
Si llu to dara to si lewa
llu tie emi ko le gbagbe lai
Gbogbo Ifaki kesima yo
Orire wa yoo bawa kale
4. Ohun ta se loni itan ni
Ajeji Owo ko gberu dori
Wa ko ni sowa lori
Efife han si ara yin
A o ko ere oko dele
5. Omo Ifaki to wa lajo
E ma kore rere wale
Ranti pe ile labo oko
E o kore oko dele
lle koko leye oko nke
E mase gbagbe Ili Ifaki
Tel: +08071149949 / Email: info@ifaki-ekiti.com